odi mejeji loto oluwa re joko
adifafun ologun inu igbo
owu ruru ja na gbamu enu ibon
nibon fi segun
ODI MEJI
IBA
HOMAGE
Iba O
Homage to Olodumare
Olodumare Oba ajiki
Olodumare, Divine Ruler who must be reverently praised every morning (unmovable, unchanging)
Edumare Oba a ji ge
Edumare (Orunmila), the most respected with adoration,
Ogege Oba tiin gbele aye gun
The pivot of life equilibrium
Ogbagba nla Oba tolode-Orun
The grand commander of the cosmic zone
Iba O
Homage to
Ati yo ojo
The rising of the Sun
Ati wo oorun
The setting of the Sun
Iba kutukutu awo owuro
Kutukutu, the priest of the early Dawn
Ganrin Ganrin Awo osan gangan
Ganrin Ganrin , priest of the Noon
Winrin winrin Awo Oru
Winrin winrin, priest of the Night
Ati okuku-su-wii, Awo Oganjo
Okuku-su-wi, priest of the mid-night
Iba Sango, Oluorojo, bambi-arigba ota segun
Homage to Sango, Oluorojo, Bambi, the Orisa of Thunder with many thunderbolts
Iba Haawa, Iba Gambe-Olu,
Homage to Haawo and Gambe-Olu wives of Sango
Iba Oya Oriri, Obinrin gbongbonran tii n yoko re loko ebu
Homage to Oya Oriri, the powerful woman that recused her husband from ridicules,
Iba Oke ganga, Oke ganga
Homage to Oke ganga, Oke ganga
Iba Aganju
Homage to Orisa Aganju
Iba Mojelewu
Homage to Orisa Mojelewu
Iba Okeere
Homage to Orisa Okeere
Iba Yemoja, Iba odo Ogun
Homage to Orisa Yemoja and river Ogun
Iba Osaara, Iba Toorosi
Homage to Osaara and Toorosi, Sango's Godmothers
Iba Iyalode lode oro
Homage to Iyalode, the custodian of Oro (Oro town)
Iba Moremi lode Ofa
Homage to Moremi custodian of Ofa (Ofa town)
Iba Oba
Homage to Orisa Oba the faithful and committed wife of Sango,
Iba O, Obatala, Oba taasa
Homage to Obatala King of Orisa Oba Taasa
No comments:
Post a Comment